top of page
  • Writer's pictureBosede

ÀÌSÀN ÌRÚJÚ ÀTÏ ÌDÀMÚ (DEMENTIA)

Updated: May 15, 2021


Alzheimer ni oruko òjògbón ti o se iwadi aisan yi. Aisan Ìrújú ti o wópò ju ni Alzheimer's disease. Èròja ara ti oyinbo npe ni "neurotransmitters" kó ipa pàtàkì nínu ìsípòpadà işan, ìrònú, ìrántí ati àwön işę õpõlõ miran. Ti Iyè ba lo sílę, agbára ati ronu yöo sá fęrę.

Apęęrę aisan yi:

1. Ìgbàgbé tabi aile danurò

2. Àigbóràn

3. Wíwú lé

4. Ìbínú

5. Ìkójú böle onile

6. Ìsokúso tabi àtònù

7. Àrìnká

8. Èdè àiyedè ati ìjà òdì ati Beebe lo

Ti o ba ri apeere wönyíi, tètè kési dókítà re fún àyęwò tabi ki o pe nömba yii fun imoran

1300775870

- Bosede Adetifa

8 views0 comments

Recent Posts

See All

Ọ̀RỌ̀ ÀPỌ́NLÉ - ADVERB

Ọ̀RỌ̀ ÀPỌ́NLÉ (Adverb) ọ̀rọ̀ àpọ́nlé ni ó ń fún wa ní ìtumọ̀ kíkún lórí ọ̀rọ̀ ìṣe nínú gbólóhùn. Fún àpẹẹrẹ : Ìyá àgbà sùn fọnfọn (sùn jẹ́ ọ̀rọ̀ ìṣe nígbà tí fọnfọn jẹ́ ọ̀rọ̀ àpọ́nlé) Ǹjẹ́ ẹyin náà lè

Names by Nature

*Orúkọ àmútọ̀runwá* 1. Taiwo (Tọ́-ayé-wò) - first of twins 2. Kehinde - last born of twin 3. Ìdòwú - a child born after the twins 4. Àlàbá - a child born after Ìdòwú 5. Ìdògbé - a child born after Àlà

Orúkọ Àmùtọ̀runwá

*Orúkọ àmútọ̀runwá* 1. Taiwo (Tọ́-ayé-wò) - first of twins 2. Kehinde - last born of twin 3. Ìdòwú - a child born after the twins 4. Àlàbá - a child born after Ìdòwú 5. Ìdògbé - a child born after Àlà

Comments


bottom of page