top of page
  • Writer's pictureBosede

Àṣà ayò títa (the culture of Ayò Game)

Updated: Nov 8, 2020

Yorùbá máaṅta ta ayò lẹ́yìn iṣẹ́ - Yorùbá people play ayò game after work

Ọpọ́n onígi tí o níhò mẹ́fà lọ́na mèjì ni a fi n taá - we use a wooden box with 6 holes either side to play the game

Ní ìgbàmíràn ẹ̀wẹ̀, a máa n gbẹ́ ihò méjila (mẹ́fa ní ọwọ́ ọ̀tun àti òsì) sí orí ilẹ̀ pẹ̀pẹ̀, pàápàá jùlọ nígbàtí kò bá sí ọpọ́n onígi - other times we can dig the 12 shallow holes on the ground directly (6 holes on right and 6 on left) when there is no wooden box.

Ènìyàn méjì ni ó máa ṅta ayò ọlọ́pọ́n- two people play the wooden ayó game.

Èso ayò mẹ́rịn ni o máa nwà nínú iho kọ̀ọ̀kan tí a ṅpè ní ilé - there are 4 seeds in each hole called house.

Ẹni àkọ́ƙọ́ yoo ta láti ọwọ́ òsì sí ọwọ́ ọ̀tun. YÓò si jẹ ọmọ ayò méjì tàbí mẹ́ta nínú ilé alátakò rẹ̀ - The first player wil start playing by dropping one seed in each hole starting from left side to right side. If 1 or 2 seeds are met in the opponent's house, you earn it as yours.

Ẹnití ó ba ní ọmọ ayò ti ó pọ̀jù ni ógbé igbá orókè - whosoever has more ayò seeds is the winner.

30 views0 comments

Recent Posts

See All

Ọ̀RỌ̀ ÀPỌ́NLÉ - ADVERB

Ọ̀RỌ̀ ÀPỌ́NLÉ (Adverb) ọ̀rọ̀ àpọ́nlé ni ó ń fún wa ní ìtumọ̀ kíkún lórí ọ̀rọ̀ ìṣe nínú gbólóhùn. Fún àpẹẹrẹ : Ìyá àgbà sùn fọnfọn (sùn jẹ́ ọ̀rọ̀ ìṣe nígbà tí fọnfọn jẹ́ ọ̀rọ̀ àpọ́nlé) Ǹjẹ́ ẹyin náà lè

Names by Nature

*Orúkọ àmútọ̀runwá* 1. Taiwo (Tọ́-ayé-wò) - first of twins 2. Kehinde - last born of twin 3. Ìdòwú - a child born after the twins 4. Àlàbá - a child born after Ìdòwú 5. Ìdògbé - a child born after Àlà

Orúkọ Àmùtọ̀runwá

*Orúkọ àmútọ̀runwá* 1. Taiwo (Tọ́-ayé-wò) - first of twins 2. Kehinde - last born of twin 3. Ìdòwú - a child born after the twins 4. Àlàbá - a child born after Ìdòwú 5. Ìdògbé - a child born after Àlà

Comments


bottom of page