top of page
  • Writer's pictureBosede

Ìró Álífábẹ́tì Yorùbá

ÌRÓ ÁLÍFÁBẸ̀TÌ YORÙBÁ

ó ṣe pàtàkì kí a mọ ìró ohùn kí á lè ṣe àkọsílẹ̀ tí ó péye tí yóò sì ní ìtumọ̀ tí a bá sọ ọ́ jáde.

Fún àpẹẹrẹ:

Àwọn fáwẹ̀lì ni yóò gbà Àmín gbólóhùn sórí láti fún àdàpọ̀ kọ́nsónantì àti fáwẹ̀lì ní ìtumọ̀.

Àwọn fáwẹ̀lì méje yí ni a npe ni fáwẹ̀lì Àiránmúpè

*A E Ẹ I O Ọ U*

Àwọn tí isale yí ni n pe ni fáwẹ̀lì Àránmúpè

*AN ẸN IN ỌN UN*

Ẹ lọ mọ ÁLÍFÁBẸ̀TÌ yín dáadáa.

Ó dìgbà.

3 views0 comments

Recent Posts

See All

Ọ̀RỌ̀ ÀPỌ́NLÉ - ADVERB

Ọ̀RỌ̀ ÀPỌ́NLÉ (Adverb) ọ̀rọ̀ àpọ́nlé ni ó ń fún wa ní ìtumọ̀ kíkún lórí ọ̀rọ̀ ìṣe nínú gbólóhùn. Fún àpẹẹrẹ : Ìyá àgbà sùn fọnfọn (sùn jẹ́ ọ̀rọ̀ ìṣe nígbà tí fọnfọn jẹ́ ọ̀rọ̀ àpọ́nlé) Ǹjẹ́ ẹyin náà lè

Names by Nature

*Orúkọ àmútọ̀runwá* 1. Taiwo (Tọ́-ayé-wò) - first of twins 2. Kehinde - last born of twin 3. Ìdòwú - a child born after the twins 4. Àlàbá - a child born after Ìdòwú 5. Ìdògbé - a child born after Àlà

Orúkọ Àmùtọ̀runwá

Comments

bottom of page