top of page
  • Writer's pictureBosede

ÌRORA ATI ÌWÙWÀSÍ

Updated: May 15, 2021


Ìrora jé òķan gbòógì nínú ohun tí ńfa ìwà yíyípadà gégé bí ìwáàdí tí àwön òjògbón "ĎSA se ni àipé yi.

Sísõ bí ìrora tipò to, mímo òdiwön ìrora láti mo iru ìtojú tí o yę ję ìsoro fún onísę ìwòsan. Bíi õgorin ninu ogórún awon arugbo ni o wà ninú ìrora ti won kò si le se àlàyé bi o se nse won.

Kòsí gègé kan pàtó láti físe òdíwön ìrora fun awon àgbà ti kò le şàlàye bi ara se n ñi wön

Báwo ni ìrora se nfa ìwà yíyípadà

1. Ìrora òjijì le fa ìsubu, aile ģbéra nile ati ìfarapa

2. Ìrora olojo pipe le fa idubule aisan ati arun öpolo

Lo rí dókítà re ti ara ba n ro ö oo. Ijafara lewu.

- Bosede Adetifa

7 views0 comments

Recent Posts

See All

Ọ̀RỌ̀ ÀPỌ́NLÉ - ADVERB

Ọ̀RỌ̀ ÀPỌ́NLÉ (Adverb) ọ̀rọ̀ àpọ́nlé ni ó ń fún wa ní ìtumọ̀ kíkún lórí ọ̀rọ̀ ìṣe nínú gbólóhùn. Fún àpẹẹrẹ : Ìyá àgbà sùn fọnfọn (sùn jẹ́ ọ̀rọ̀ ìṣe nígbà tí fọnfọn jẹ́ ọ̀rọ̀ àpọ́nlé) Ǹjẹ́ ẹyin náà lè

Names by Nature

*Orúkọ àmútọ̀runwá* 1. Taiwo (Tọ́-ayé-wò) - first of twins 2. Kehinde - last born of twin 3. Ìdòwú - a child born after the twins 4. Àlàbá - a child born after Ìdòwú 5. Ìdògbé - a child born after Àlà

Orúkọ Àmùtọ̀runwá

*Orúkọ àmútọ̀runwá* 1. Taiwo (Tọ́-ayé-wò) - first of twins 2. Kehinde - last born of twin 3. Ìdòwú - a child born after the twins 4. Àlàbá - a child born after Ìdòwú 5. Ìdògbé - a child born after Àlà

Comments


bottom of page