top of page
  • Writer's pictureBosede

Ömö ni ìgbęyìn öla

Updated: May 15, 2021

Ömö ni ìgbęyìn òla

Ömö lará, ömö lérè

Bí a búni lęyìn bá ò gbó

Sé ömö eni nii so fún ni

Kí la tún ń fowó rà

Tí ó lékè ömö

Inákú ó fërú bojú

Ògędę kú, ó fõmõ rę rópò

Bí aládii kò sí nílé,

Ömö nii jogún ębu

Ömö ni yoo jogún ęwà lódò wa

10 views1 comment

Recent Posts

See All

Ọ̀RỌ̀ ÀPỌ́NLÉ - ADVERB

Ọ̀RỌ̀ ÀPỌ́NLÉ (Adverb) ọ̀rọ̀ àpọ́nlé ni ó ń fún wa ní ìtumọ̀ kíkún lórí ọ̀rọ̀ ìṣe nínú gbólóhùn. Fún àpẹẹrẹ : Ìyá àgbà sùn fọnfọn (sùn jẹ́ ọ̀rọ̀ ìṣe nígbà tí fọnfọn jẹ́ ọ̀rọ̀ àpọ́nlé) Ǹjẹ́ ẹyin náà lè

Names by Nature

*Orúkọ àmútọ̀runwá* 1. Taiwo (Tọ́-ayé-wò) - first of twins 2. Kehinde - last born of twin 3. Ìdòwú - a child born after the twins 4. Àlàbá - a child born after Ìdòwú 5. Ìdògbé - a child born after Àlà

Orúkọ Àmùtọ̀runwá

1 Comment

doyletsanusy
Mar 18, 2021

Béèni... èdùwà jòwó jékí omo rere gbèyìn gbogbo wa. Àse🤲🏾

Like
bottom of page