top of page
  • Writer's pictureBosede

Ọ̀RỌ̀ ìdúpẹ́

ÈYÍ NI LÁTI DÚPẸ́ LỌ́WỌ́ GBOGBO ÀWỌN ONÍGBỌ̀WỌ̀ WA LORI FỌ́NRÁN YI BÍ ỌDÚN ṢE NLỌ SÓPIN

ADÚPẸ́ fún eyín tí ẹ ti gbé wa lápá sókè nínú ọdún yí. Kò sí ìrẹ̀wẹ̀sì kankan pelu yín ní asiko àjàkálẹ̀ covid. Ojúu pé, ọlá yóò dára Lẹfì wo àsìkò náà, èyí jẹ́ ìwúrí fún wa. Ẹ ṣé o.

ADÚPẸ́ fún ẹyin apanilẹrin, inú wa dùn pé ẹ darapọ̀ mo wà. Ẹ ṣe

ADÚPẸ́ lọ́wọ́ ẹyin amòye, fún ìfòye gbọ́rọ̀ kalẹ̀ yín, ó wú wá lórí gan an ni

ADÚPẸ́ lọ́wọ́ àwọn onilaja tí ó jẹ́ ki orí àpè yi o dàrú. Ẹ seun fún ìṣe tí ẹ ń ṣe lábẹ́lẹ̀. A dúpẹ́ .

ADÚPẸ́ fún àwọn olùwò bóṣe ń lọ. Mímọ pé ẹ wá lẹ́yìn wá fi wá lọ́kàn balẹ̀, A mọ rírí yín o, ẹ seun


ADÚPẸ́ lọ́wọ́ àwọn ẹlẹ́ṣìn ọkàn ó jọ̀kan, àwọn amuludun, àwọn oníṣòwò, àwọn onisẹ́ owó, ọ̀dọ́mọdé ati àgbà tí wọn ń tẹ́lẹ̀ òfin wá láìṣe àní àní, wọn si tún tesiwaju láti bawa ṣíṣe pọ̀, pelu àdúrà àṣeyege. ADÚPẸ́

ADÚPẸ́ fún àwọn tí a ó dárúkọ ṣùgbọ́n tí wọn tí kópa nínú ìtẹ̀síwájú wá. A mọ lóore ó.

ADÚPẸ́ lọ́wọ́ àwọn olùṣàkóso fọ́nrán yí fún ìyípadà tí wọn ń mú bá igbe ayé wa nípa ìwà àti ọ̀rọ̀ pẹ̀lẹ́ wọn. Láìsí ẹ̀yin, kò le sí àwa. A dúpẹ́ gidi ó.

A dúpẹ́ o, Ọdún Ayọ̀ ni ẹ óò ṣe o. Àṣẹ

Èmi ni Tiyín ni tòótọ́ ,

Iyaafin Bosede Adetifa

7 views0 comments

Recent Posts

See All

Ọ̀RỌ̀ ÀPỌ́NLÉ - ADVERB

Ọ̀RỌ̀ ÀPỌ́NLÉ (Adverb) ọ̀rọ̀ àpọ́nlé ni ó ń fún wa ní ìtumọ̀ kíkún lórí ọ̀rọ̀ ìṣe nínú gbólóhùn. Fún àpẹẹrẹ : Ìyá àgbà sùn fọnfọn (sùn jẹ́ ọ̀rọ̀ ìṣe nígbà tí fọnfọn jẹ́ ọ̀rọ̀ àpọ́nlé) Ǹjẹ́ ẹyin náà lè

Names by Nature

*Orúkọ àmútọ̀runwá* 1. Taiwo (Tọ́-ayé-wò) - first of twins 2. Kehinde - last born of twin 3. Ìdòwú - a child born after the twins 4. Àlàbá - a child born after Ìdòwú 5. Ìdògbé - a child born after Àlà

Orúkọ Àmùtọ̀runwá

*Orúkọ àmútọ̀runwá* 1. Taiwo (Tọ́-ayé-wò) - first of twins 2. Kehinde - last born of twin 3. Ìdòwú - a child born after the twins 4. Àlàbá - a child born after Ìdòwú 5. Ìdògbé - a child born after Àlà

Comments


bottom of page