top of page
  • Writer's pictureBosede

Ọ̀RỌ̀ ORÚKỌ

Oríṣi ọ̀rọ̀ orúkọ ní o wà. Ǹjẹ́ o lè dárúkọ wọn, Kí ó sì ṣe àpẹẹrẹ?

1. Ọ̀rọ̀ orúkọ Àrídìmú (concrete noun) - bàtà, ilé, aṣọ, tábìlì 🛖👚🥿🪑🏆🎁🫖🔪

2. Ọ̀rọ̀ orúkọ afòyémọ̀ (abstract noun) - ìrànlọ́wọ́, Ayọ̀, ìgbàgbọ́, ìyànjẹ, àánú 🤣🥰🦹🤼

3. Ọ̀rọ̀ orúkọ aṣeékà (countable noun) - ìlú, akẹ́kọ̀ọ́, ìwé, abọ́, àpótí 🪵👨‍👨‍👦‍👦🍵🏘️🚚⚽

4. Ọ̀rọ̀ orúkọ Aláìseekà (un countable now) - iyanrìn, omi, ẹ̀wà, irun

12 views0 comments

Recent Posts

See All

Ọ̀RỌ̀ ÀPỌ́NLÉ - ADVERB

Ọ̀RỌ̀ ÀPỌ́NLÉ (Adverb) ọ̀rọ̀ àpọ́nlé ni ó ń fún wa ní ìtumọ̀ kíkún lórí ọ̀rọ̀ ìṣe nínú gbólóhùn. Fún àpẹẹrẹ : Ìyá àgbà sùn fọnfọn (sùn jẹ́ ọ̀rọ̀ ìṣe nígbà tí fọnfọn jẹ́ ọ̀rọ̀ àpọ́nlé) Ǹjẹ́ ẹyin náà lè

Names by Nature

*Orúkọ àmútọ̀runwá* 1. Taiwo (Tọ́-ayé-wò) - first of twins 2. Kehinde - last born of twin 3. Ìdòwú - a child born after the twins 4. Àlàbá - a child born after Ìdòwú 5. Ìdògbé - a child born after Àlà

Orúkọ Àmùtọ̀runwá

Comments

bottom of page