top of page
  • Writer's pictureBosede

Ọdún Òmìnira

Akú dédé àsìkò yìí o gbogbo ẹ̀yin òbí i wa. Akú àjọ̀dún òmìnira ti Nigeria, ẹ̀mí á ṣọ̀pọ̀ ẹ̀ láyé.

Orúkọ mi ni Ayọ̀míde Adetifa. Kókó ọ̀rọ̀ méjì ni mo fẹ́ sọ lè lórí lónìí yìí.

Àkọ́kọ́ ni nípa abẹ́rẹ́ àjẹsára fún àrùn korona tí a mọ̀ sí Covid-19. Àrùn yìí kò mọ ọmọdé bẹ́ẹ̀ni kò mọ àgbàlagbà, ó sì tí ṣekú pa ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn gẹ́gẹ́ bí a ṣe mọ̀. Láti leè dẹ́kun rẹ̀, ó ṣe pàtàkì kí á fọwọ́ sọ wọ́pọ̀ pẹ̀lú ìjọba kí a gbabẹ́rẹ́ náà fún àǹfàní ara wa àti àwọn tí ó sún mọ́ wá. A ò ní lùgbàdì àrùn COVID ó.


Yàtọ̀ sí èyí, a fẹ́ rọ ẹ̀yin òbí wa láti máa gba àwa ọmọ yín ní ìyànjú nípa kíkọ́ àti sísọ èdè abínibí síwa lóòrè kóòrè àti kíkọ wa ní àṣà, nítorí pé ọmọ tó bá sọ lénù, óso àpò ìyà kọ́. Eléyìí ṣe pàtàkì púpọ̀ fún ìtànká àti ìbúgbòrò

30 views0 comments

Recent Posts

See All

Ọ̀RỌ̀ ÀPỌ́NLÉ - ADVERB

Ọ̀RỌ̀ ÀPỌ́NLÉ (Adverb) ọ̀rọ̀ àpọ́nlé ni ó ń fún wa ní ìtumọ̀ kíkún lórí ọ̀rọ̀ ìṣe nínú gbólóhùn. Fún àpẹẹrẹ : Ìyá àgbà sùn fọnfọn (sùn jẹ́ ọ̀rọ̀ ìṣe nígbà tí fọnfọn jẹ́ ọ̀rọ̀ àpọ́nlé) Ǹjẹ́ ẹyin náà lè

Names by Nature

*Orúkọ àmútọ̀runwá* 1. Taiwo (Tọ́-ayé-wò) - first of twins 2. Kehinde - last born of twin 3. Ìdòwú - a child born after the twins 4. Àlàbá - a child born after Ìdòwú 5. Ìdògbé - a child born after Àlà

Orúkọ Àmùtọ̀runwá

*Orúkọ àmútọ̀runwá* 1. Taiwo (Tọ́-ayé-wò) - first of twins 2. Kehinde - last born of twin 3. Ìdòwú - a child born after the twins 4. Àlàbá - a child born after Ìdòwú 5. Ìdògbé - a child born after Àlà

Comments


bottom of page