top of page
  • Writer's pictureBosede

Simple Yoruba sentences

Ẹ káàrọ̀ o (good morning), ṣé dáadáa lají (did you wake up well? ).

Ẹ jẹ́ kí á kọ́ àwọn ọ̀rọ̀ kéékèèké wọ̀nyí:

(Let's learn these simple words.)

1. Mo - I (pronoun 'I')

2. Fẹ́ - want (Love)

3. Wẹ̀ - shower/bathe

4. Jẹ - eat

5. Lọ - go


Kí á lò wọ́n nínú gbólóhùn - *let's* (kí) *use* (lò) *them* (wọn) *in* (nínú) *sentences* (gbólóhùn).


1. Mo fẹ́ wẹ̀ - I want to shower


2. Paige ń (is) wẹ̀ - Paige is bathing.


3. Mo ti (had) wẹ̀ - I had bathed.

4. Mo ti (have) jẹun - I have eaten

5. Mo ń (am) gbàlẹ̀ - I am sweeping


It is your turn now to use the following verbs in sentences

Ó yá ó, ìwọ náà lọ àwọn ọ̀rọ̀ ìṣe wọ́nyí nínú gbólóhùn


1. sùn - sleeping

2. jó - dancing

3. kọrin - singing

4. Rẹ́ẹ̀rín - laughing

5. Rìn - walk

EnJoy your day

76 views0 comments

Recent Posts

See All

Ọ̀RỌ̀ ÀPỌ́NLÉ - ADVERB

Ọ̀RỌ̀ ÀPỌ́NLÉ (Adverb) ọ̀rọ̀ àpọ́nlé ni ó ń fún wa ní ìtumọ̀ kíkún lórí ọ̀rọ̀ ìṣe nínú gbólóhùn. Fún àpẹẹrẹ : Ìyá àgbà sùn fọnfọn (sùn jẹ́ ọ̀rọ̀ ìṣe nígbà tí fọnfọn jẹ́ ọ̀rọ̀ àpọ́nlé) Ǹjẹ́ ẹyin náà lè

Names by Nature

*Orúkọ àmútọ̀runwá* 1. Taiwo (Tọ́-ayé-wò) - first of twins 2. Kehinde - last born of twin 3. Ìdòwú - a child born after the twins 4. Àlàbá - a child born after Ìdòwú 5. Ìdògbé - a child born after Àlà

Orúkọ Àmùtọ̀runwá

*Orúkọ àmútọ̀runwá* 1. Taiwo (Tọ́-ayé-wò) - first of twins 2. Kehinde - last born of twin 3. Ìdòwú - a child born after the twins 4. Àlàbá - a child born after Ìdòwú 5. Ìdògbé - a child born after Àlà

Comments


bottom of page