top of page
  • Writer's pictureBosede

Using 'i want' in Yoruba sentences

Lílo 'mo fẹ́' nínú-un gbólóhùn kéékèèké - Use of 'I want to' in

simple sentences.

Kíni o fẹ́ ṣe? What do you want to do?

Kini o n se? What are you doing? 

1. Eat - Mo fẹ́ jẹun (I want to eat) 

 Mo n jẹun (I am eating) 

2. Sleep - Mo fe sun (I want to sleep) 

Mo n sun (I am sleeping) 

3. Read - Mo fe ká iwe kan (I want to read a book) 

Mo n ka ìwé kan (I am reading a book) 

Mo n ka iwe mi(my) (I am reading my(mi) book) 

4. Bathe - Mo fe we (I want to bathe/shower) 

Mo n we I am bathing

5. Run - Mo fe sare (I want to run) 

Mo n sare I am running

6. Defecate/ toilet (Mo fẹ́ yàgbẹ́ (I want to poo/defecate) 

Mo n yagbe (I am 💩 pooing/defecating) 

7. Jump - Mo fẹ́ fo (I want to jump) 

Mò ń fò (I am jumping) 

10 views0 comments

Recent Posts

See All

Ọ̀RỌ̀ ÀPỌ́NLÉ - ADVERB

Ọ̀RỌ̀ ÀPỌ́NLÉ (Adverb) ọ̀rọ̀ àpọ́nlé ni ó ń fún wa ní ìtumọ̀ kíkún lórí ọ̀rọ̀ ìṣe nínú gbólóhùn. Fún àpẹẹrẹ : Ìyá àgbà sùn fọnfọn (sùn jẹ́ ọ̀rọ̀ ìṣe nígbà tí fọnfọn jẹ́ ọ̀rọ̀ àpọ́nlé) Ǹjẹ́ ẹyin náà lè

Names by Nature

*Orúkọ àmútọ̀runwá* 1. Taiwo (Tọ́-ayé-wò) - first of twins 2. Kehinde - last born of twin 3. Ìdòwú - a child born after the twins 4. Àlàbá - a child born after Ìdòwú 5. Ìdògbé - a child born after Àlà

Orúkọ Àmùtọ̀runwá

*Orúkọ àmútọ̀runwá* 1. Taiwo (Tọ́-ayé-wò) - first of twins 2. Kehinde - last born of twin 3. Ìdòwú - a child born after the twins 4. Àlàbá - a child born after Ìdòwú 5. Ìdògbé - a child born after Àlà

Commentaires


bottom of page